Irọ́ o! Ṣúgà nìkan kọ́ ló ma ń fa ẹ̀jẹ̀ ríru Attribution+  — Gẹ́gẹ́ bí àjọ tó ń rí sí ètò ìlera lágbayé (WHO), ẹ̀jẹ̀ ríru (aipatẹ́sọ́nù) ma ń wáyé nígbà tí ìfunpá ènìyàn... ... Dubawa 1 d
Kò sí ẹ̀rí tó dájú pé akọ aláǹgbá le wo ikó-ife Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Ẹnìkan tó dá sí  ètò rédìò kan ṣọ pé jíjẹ akọ aláǹgbá le wo àrùn ikọ́-ife. ... Dubawa 2 d
Àrùn onígbáméjì tó bẹ́ sílẹ̀ ní Nàìjíríà àti ọ̀nà márùn-ún tí a leè gbà dáàbò bo ara wa Attribution+  — Ẹnu ọjọ́ mẹ́ta yìí ni àrùn onígbáméjì (Cholera) tún bẹ́ sílẹ̀ ní orílè-èdè Nàìjíríà, tó sì ń jà bíi ìjì. Ìwádìí fi yé wa wípé, ó lé ní ẹgbẹ̀rún kan ìṣẹ̀lẹ̀ ... Dubawa 3 d
Olórin Calypso Trinidad àti Tobago, Black Stalin, àwòkọ́ṣe ‘ọkùnrin Caribbean,’ jáde láyé ní ẹni Ọdú... CC BY  — Ògbó aládàánìkàn ronú tó gbóná àti olùpilẹ̀sẹ̀ ọ̀rọ̀ orin, ní gbogbo ìlàkàkà rẹ Stalin gbìyànjú láti jẹ́ kí ohun gbogbo lọ déédé. ... Global Voices 5 d
Ìdílé Kútì tí ń fẹ̀hónúhàn nípasẹ̀ orin àti àwọn ọmọ Nigeria mìíràn tí wọ́n kọrin táko ẹlẹ́yàmẹ̀yà CC BY  — Àwọn ìdílé Kútì ti gbógun ti àwọn adarí burúkú nípasẹ̀ orin. Bákan náà, àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria bí Sonny Okosun, Majek Fashek àti Onyeka Onwenu jà láti rí i pé wọ́n dá Nelson Mandela sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n. ... Global Voices 5 d
‘Ìkòròdú bois’ ṣàfihàn bí àwọn gbàgede ẹ̀rọ-ayélujára ṣe ń ṣe ìgbélárugẹ àwọn eré àgbéléwò orílẹ̀-èd... CC BY  — Pẹ̀lú irinṣẹ́ tí kò tó àti àwọn àmúlò irinṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá, ikọ̀ ‘Ìkòròdù Bois’ ṣe ìsínjẹ àti àwàdà àwọn eré Hollywood àti Nollywood tí ó ti di èrò yà wá á wò ó kárí ayé lórí àwọn gbàgede ìbáraẹnidọ́rẹ̀ẹ́. ... Global Voices 5 d
Bí ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù Atlas Lions ti Morocco ṣe fi ìtàn balẹ̀ nínú ìdíje ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀... CC BY  — Ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù Morocco, Atlas Lions ni ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù àkọ́kọ̀ ní ilẹ̀ Áfríkà àti ilẹ̀ Lárúbáwá tí yóò kọ́kọ́ dé ìpele tí ó kángun sí ìparí nínú ìdíje Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé. ... Global Voices 5 d
Àjọ tí ó ń rí sí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ní Turkey ní àwọn obìnrin ò le dá nìkan rin ìrìn-àjò CC BY  — Ìgbà àkọ́kọ́ tí àjọ ẹ̀sìn ní ìlú Turkey yóò lépa àwọn obìnrin àti òmìnira wọn kọ́ lèyìí, tí ó sì tún ń yẹpẹrẹ wọ́n láwùjọ. ... Global Voices 5 d
Ó rọrùn, lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, ó sì bani nínú jẹ́ — òṣùwọ̀n àwọn àjọ̀dún CC BY  — " ... Ohun tí mo ní pẹ̀lú Ọjọ́ Àìsùn Ọdún tuntun wá láti èrò ìgbà èwe, èrò tó fi yé mi pé àwọn idán àràmàndà lè ṣẹlẹ̀." ... Global Voices 5 d
Kò sí ẹ̀rí tó dájú pé akọ aláǹgbá le wo ikó-ife Attribution+  — Ìwádìí láti ọwọ́ àwọn oníṣègùn òyìnbó fì dí rẹ̀ mú lẹ̀ pé kò sí àrídájú pé jíjẹ akọ aláǹgbá le wo àrùn ikó-ife. Ófégé ni ọ̀rọ̀ náà... ... Dubawa 5 d
Ìdáhùn sí ìbéèrè mẹ́rin lórí ooru àmúlàágùn t’ó gbòde kan Attribution+  — Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló ń kérora ooru àmújù tí ó gbòde kan, tí oníkálukú sì ń fi àìdunú wọn hàn ní oríṣiríṣi ọ̀nà. Bí àwọn àgbàlagbà ṣe ń k'áyàsókè lórí ọ̀rọ̀ ... Dubawa 6 d
Ǹjẹ́ Gómìnà Adélékè buwọ́lu bíliọnù lọ́nà Ọgbọ́n Náírà fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe ní'lú  Ẹdẹ? Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Ọmo ẹgbẹ́ òṣèlú oní’tèsìwájú (APC) làti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, lórí ètò rédìò kan, wípé Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adémólá Adélèké buwọ́lu N30 bíliọnù fún iṣẹ́ ... Dubawa 6 d
Ṣé ó dára kí a fi ọṣẹ fọ oúnjẹ? Attribution+  — Oríṣiríṣi agbekale ilana imototo lo tẹ̀lé àjàkálẹ̀ ààrùn COVID-19, biotilẹjẹpe òmíràn kò bójúmu. Òkan lára wọn ni ki a máa... ... Dubawa 1 w
Irọ́ ni! Àgbálùmọ̀ kò le wo akọ jẹ̀díjẹ̀dí, àrùn ẹ̀jẹ̀ ríru Attribution+  — Àhèsọ: Fọ́nrán kan láti ọwọ́ arashadyworldwide lójú òpó TIk Tok tí àwọn èèyàn tí wọ́n lé ní 77 thousand ti wò, tí wọ́n tún fi ṣọ wọ́ ló jú òpó WhatsApp, pé ... Dubawa 1 w
Irọ́! Kò sí òògùn kan pàtó fún àìsàn olóde Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Aṣàmúlò TikTok kan wípé ọtí ìbílẹ̀ àti ẹfun le wo àìsàn olóde (measles). ... Dubawa 1 w
Ǹjẹ́ jíjẹ ọ̀gẹ̀dẹ̀ alábàwọ́n le ṣokùnfa àrùn jẹjẹrẹ? Attribution+  — Gẹ́gẹ́ bí àjọ elétò ìlera àgbáyé “WHO” ṣe sọ, ààrùn jẹjẹrẹ ló ń ṣokùnfa ikú ènìyàn kan nínú ènìyàn mẹ́fà lágbayé. Lẹyìn jẹjẹrẹ... ... Dubawa 1 w
Ìròyìn aṣnilọ́nà gbòde kan lórí ètò oúnjẹ ọ̀fẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní'pìnlẹ̀ Ọ̀ṣun Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Gómìnà Adélékè ti fagilé ètò óúnjẹ ọ̀fẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé’wé alákọ́bèrẹ̀. ... Dubawa 2 w
Òtítọ́ ni! Owó oṣù òṣìṣẹ́ tó kéré jùlọ ní Ghana, Benin Republic pọ̀ju ti Nàìjíríà lọ Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Ẹnìkan tó dá sí ẹ̀tò kan lórí rédíò sọ pé owó oṣù òṣìṣẹ́ tó kéré jùlọ lórílẹ̀-èdè Ghana àti Benin Republic pọ̀ju ti Nàìjíríà lọ. ... Dubawa 2 w
Ǹjẹ́ Bobrisky wà ní àtìmọ́lé EFCC fún ẹ̀sùn Owó kíkójẹ? Attribution+  — Àhesọ: Ìròyìn kan tí ó lédè ní orí ìtàkùn Instagram kan tí ó ǹjẹ́ Yoruba Nation News ni ó sọ wípé Bobrisky tí wà ní àtìmọ́lé àwọn EFCC fún ẹ̀sùn Owó kíkójẹ ní ... Dubawa 2 w
Ǹjẹ́ ọpọlọ aláboyún ma ń súnkì kí ó tó bímọ? Attribution+  — Àhesọ: Aṣàmúlò ìkànnì X kan wípé ọpọlọ obìrin má ń súnkì nígbà tí ó bá wà nínú oyún. Ó sì nílo oṣù mẹ́fà láti padà sí bí ó ṣe yẹ kó wà. ... Dubawa 2 w
Ǹjẹ́ Gómìnà Adélékè buwọ́lu bíliọnù lọ́nà Ọgbọ́n Náírà fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe ní'lú  Ẹdẹ? Attribution+  — Ìwádìí fì’di rẹ̀ múlè pé Gómìnà Adémólá Adélékè kò buwọ́lu owó fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe mìíràn àyàfi èyí tó wà nínú... ... Dubawa 2 w
Ǹjẹ́ ọpọlọ aláboyún ma ń súnkì kí ó tó bímọ? Attribution+  — Oyún ma ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí ọlẹ̀ inú bá sọ sínú ilé ọmọ tí a mọ̀ sí utérọ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ aláboyún kìí rí àmì kan pàtó lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀... ... Dubawa 2 w
Orin ẹ̀hónú: àwọn ọ̀dọ́mọdé òǹkọrin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kọrin tako ìwà ìrẹ́jẹ láwùjọ CC BY  — Àwọn ọ̀dọ́mọdé olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tẹ̀síwájú nínú àṣà kíkọ orin tako ìrẹ́jẹ láwùjọ. Èhónú #EndSARS ṣe ìtanijí ọkàn wọn sí ìkópa nínú ètò òṣèlú, eléyìí tí ó ti ń wòòkùn. ... Global Voices 2 w
Ọ̀rọ̀ Ààbò Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá…ní èdè wa. Àwọn Àbá láti ọwọ́ onígbèjà èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní... CC BY  — "Àǹfààní fún àwọn elédè Yorùbá ò tó nítorí kò sí àwọn ohun àmúlò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá wọ̀nyí ní èdè abínibí wọn, èyí tí ó dákun àìsí àṣà ààbò orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá tó péye láàárín àwùjọ náà." ... Global Voices 2 w
Ayédèrú ní fónrán to ṣafihan ààrẹ Tinubu níbi ti o ti sọ̀rọ̀ nipa oníwàásù TB Jóṣúà Attribution+  — Ilé-isé ìròyìn BBC ṣ’agbejade ìwádìí kan l'órí oníwàásù ti o di olóògbé, TB Jóṣúà, oludasile ilè ìjósìn Synagogue Church of All Nations... ... Dubawa 2 w
Kòsí àrídájú pé èso jínjà, ewé efinrin le pa kòkòrò aìfojúrí lára Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Fọ́nrán kan lójú òpó Facebook ṣàlàyé pé èso atale àti ewé efinrin le wo àrùn kòkòrò aìfojúrí lára. ... Dubawa 2 w
Òtítọ́ ni! Àwọn ọkùnrin Làìbéríà wà lára àwọn tó kúrú jùlọ lágbàáyé Attribution+  — Àhesọ: Àwọn ọkùnrin Làìbéríà ti wà lára àwọn mẹ́ta tí ó kéré jùlọ ní’le adúláwọ̀, àti ìdá mẹ́tàlélógún kárí ayé. ... Dubawa 2 w
Àwọn ohun t'o ní láti mọ̀ lórí ọ̀rọ̀ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà Attribution+  — Pípè fún ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà nííṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ààbò tó dojú rú tí onírúurú ìṣẹ̀lẹ̀ sì ń ṣẹlẹ̀, bíi ìjíjigbé-gbowó, ìṣekúpani, ìgbésùmòmí, olè ... Dubawa 2 w
Ǹjẹ́ Bobrisky wà ní àtìmọ́lé EFCC fún ẹ̀sùn Owó kíkójẹ? Attribution+  — Ìròyìn kan tí ó lédè ní orí ìtàkùn Instagram tí ó ǹjẹ́ Yoruba Nation News ni ó sọ wípé Bobrisky tí wà ní àtìmọ́lé àwọn... ... Dubawa 3 w
Kòsí àrídájú pé ewúro pẹ̀lú omi àgbọn le wo àrun ẹ̀dọ̀ Attribution+  — Àhesọ: Aṣàmúlò ìtàkùn ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ Facebook kan wípé mímu àpòpọ̀ ewúro àti omi àgbọn yóò pa àrun ẹ̀dọ̀ àti kídìnrín.. Tí iye àtọ̀ ọmọkùnrin bá kéré,. yóò sì ... Dubawa 3 w
Iroyin ofege àti aṣinilona gbòde kan lẹyin ìbúgbàmù to ṣẹlẹ ni Ibadan Attribution+  — Láìpẹ́ yìí, ìbúgbàmù kan mi Bódìjà ni ibile ariwa tí Ibadan, ìpínlè Óyo. Ninu atejade kan, agbẹnusọ ọlọ́pàá ipinlẹ, Adéwálé Oyefeso.... ... Dubawa 3 w
Kò sí ẹ̀rí tó dájú pé ènìyàn lè fi kanafuru àti ata ilẹ̀/aáyù fọ ile ọmọ Attribution+  — Ojú òpó kan l'órí ìkànnì ibaraẹnisọre Facebook, Fertility Guideline Group ṣàlàyé pé èèyàn lè lo kanafuru ati ata ilẹ̀/aáyù fi fọ ilé ọmọ... ... Dubawa 3 w
Ìròyìn aṣnilọ́nà gbòde kan lórí ètò oúnjẹ ọ̀fẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní'pìnlẹ̀ Ọ̀ṣun Attribution+  — Akápò ẹgbẹ́ òsèlú òní tèsíwájú APC nìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Fẹ́mi Kújẹbọ́lá lórí ètò kan “APC Reconciliation Half Hour” ní Diamond 88.5FM... ... Dubawa 3 w
Oun mẹ́fà tí o ní látí mọ nipa ìwúlò èso apálá/ kùkúńbà Attribution+  — Ọpọlọpọ ànfààní lo wa lara èso apálá/kùkúńbà, èso náà ko ni kálórì púpọ ṣùgbọ́n ó ní àwọn èròjà ajíra bíi Vitamin C, Vitamin K, eroja asaraloore (protein), ... Dubawa 4 w
Fọ́nrán àtijọ́ ni wọ́n fi ṣ’àpèjúwe ìfẹ̀hónúhàn lórí ètò ọrọ̀ ajé Nàìjíríà Attribution+  — Àhẹ̀sọ: Aṣàmúlò X pín fọ́ran kan tó kéde ìfẹ̀hónúhàn sí Tinúbú lori ètò ọrọ̀ ajé Nàìjíríà. ... Dubawa 4 w
Àyípadà ojú ọjọ́, ìjàmbá àti àwọn ohun t'o ní láti ṣe Attribution+  — Ó ṣeéṣe kí o ti ṣe àkíyèsí àwọn ǹkan bíi àìtètè rọ̀ òjò, ìṣẹ̀lẹ̀ ẹ̀kún omi, omíyalé, odò fífà tàbí gbígbẹ pátápátá, ooru àmújù, ìjì líle, àti àwọn àjàkálẹ̀ ... Dubawa 4 w
Wọ́n pẹ̀gàn àwọn ọkùnrin aperawọnlóbìnrin, gẹ́gẹ́ bí i Wúńdíá Màríà lójú ayé rẹ̀ CC BY  — "Mo jẹ́ ìyá tí ó ń tọ́ ọmọ rẹ̀. Kò sí pé ọlẹ̀ sọ nínú mi, ṣùgbọ́n fún èmi, ìyanu ni ó jẹ́." ... Global Voices 4 w
A lé òǹṣàmúlò TikTok Nekoglai láti Moscow padà sí Moldova pẹ̀lú àmì lúlù CC BY  — “Orò ìjẹ̀bi àti ìtìjú” náà ni àwọn agbófinró orílẹ̀-èdè Russia pọwọ́lé lílò rẹ̀ láti fi “àbámọ̀” náà hàn ní gbangba àti ìpayà àwọn afẹ̀hónúhàn ... Global Voices 4 w